Mobutu Sese Seko

(Àtúnjúwe láti Joseph Mobutu)

Mobutu Sésé Seko Nkuku Ngbendu wa Za Banga (14 October 1930– 7 September 1997), to gbajumo gege bi Mobutu tabi Mobutu Sésé Seko (pípè /məˈbuːtuː ˈsɛseɪ ˈsɛkoʊ/), oruko abiso Joseph-Désiré Mobutu, lo di olori orile-ede Zaire (loni gege bi Olominira Toselu ile Kongo) leyin igba to fipagbajoba lowo Joseph Kasavubu.

Mobutu Sésé Seko
Aare ile Zaire
In office
24 November 1965 – 16 May 1997
Alákóso Àgbàopolopo
AsíwájúJoseph Kasa-Vubu
Arọ́pòLaurent-Désiré Kabila
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1930-10-14)14 Oṣù Kẹ̀wá 1930
Lisala, Belgian Congo
Aláìsí7 September 1997(1997-09-07) (ọmọ ọdún 66)
Rabat, Morocco
Ọmọorílẹ̀-èdèCongolese
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPopular Movement of the Revolution
(Àwọn) olólùfẹ́Marie-Antoinette Mobutu (alaisi)
Bobi Ladawa