Joe Biden
Olóṣèlú
(Àtúnjúwe láti Joseph Robinette Biden)
Joseph Robinette Biden Jr.(tí a bí ní November 20, 1942)[2] jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílè-èdè Amerika àti Ààrẹ Amẹ́ríkà lọ́wọ́ lọ́wọ́. Ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ òsèlú "Democratic Party". Óun ni ìgbàkejì ààrẹ orílè-èdè Amerika láàrin ọdún 2009 sí 2017 lábé isejoba Ààrẹ Barack Obama, òun sì ni Senato tí ó ṣe asoju Delaware láàrin ọdún 1973 sí ọdún 2009.
Joe Biden | |
---|---|
46th President of the United States | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga January 20 2021 | |
Asíwájú | Donald Trump |
United States Senator from Delaware | |
In office January 3, 1973 – January 15, 2009 | |
Asíwájú | Caleb Boggs |
Arọ́pò | Ted Kaufman |
Chairman of the Senate Committee on the Judiciary | |
In office January 6, 1987 – January 3, 1995 | |
Asíwájú | Strom Thurmond |
Arọ́pò | Orrin Hatch |
Chairman of the International Narcotics Control Caucus | |
In office January 4, 2007 – January 3, 2009 | |
Asíwájú | Chuck Grassley |
Arọ́pò | Dianne Feinstein |
Chairman of the Senate Committee on Foreign Relations | |
In office January 4, 2007 – January 3, 2009 | |
Asíwájú | Richard Lugar |
Arọ́pò | John Kerry |
In office June 6, 2001 – January 3, 2003 | |
Asíwájú | Jesse Helms |
Arọ́pò | Richard Lugar |
In office January 3, 2001 – January 20, 2001 | |
Asíwájú | Jesse Helms |
Arọ́pò | Jesse Helms |
Member of the New Castle County Council | |
In office 1970 – 1972 | |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 20 Oṣù Kọkànlá 1942 Scranton, Pennsylvania |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Democratic Party |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Neilia Hunter (deceased; m. 1966 – 1972) Jill Jacobs (m. 1977) |
Àwọn ọmọ | Beau Biden Robert Hunter Biden Naomi Christina Biden Ashley Blazer Biden |
Residence | Number One Observatory Circle (Official) Wilmington, Delaware (Private) |
Alma mater | University of Delaware (B.A.) Syracuse University College of Law (J.D.) |
Profession | Lawyer |
Signature | |
Website | https://whitehouse.gov/administration/president-biden/ |
Wọ́n bi sí Scranton, Pennsylvania, ó sì padà kó lọ Delaware ní ọdun 1953. Ó kàwé ní Yunifásitì ti Delaware kí ó tó tesiwaju ní Yunifásitì Syracuse láti gbami eye ìmò òfin.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Àwọn Ìtókasí
àtúnṣe- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedlat082408nw
- ↑ "Joe Biden - Age, Bio, Birthday, Family, Net Worth". National Today. October 17, 2022. Retrieved January 5, 2023.