Joseph Stalin (orúko àbísọ Ioseb Besarionis dze Jughashvili ní èdè Georgia tàbí Iosif Vissarionovich Dzhugashvili ní orúko bàbá ní Russia; 18 December 1878 – 5 March 1953) lo jẹ́ Akòwé Àgbà Ẹgbẹ́ Kọ́mmústí tí Ìsòkan Sofieti fún Ìgbìmò Gbàngbà láti 1922 títí de ọjọ́ ikú re ní 1953.[1] Léyìn ikú Lenin ní 1924, o di olórí orílẹ̀-èdè Ìsòkan Sofieti.[2]


Joseph Stalin
Иосиф Виссарионович Сталин
Iosif Vissarionovich Stalin
იოსებ ბესარიონის ძე ჯუღაშვილი
Ioseb Besarionis dze Jughashvili
1st General Secretary of the Communist Party of the Soviet Union
In office
3 April 1922 – 5 March 1953
AsíwájúPosition created
Arọ́pòGeorgy Malenkov
Premier of the Soviet Union
In office
6 May 1941 – 5 March 1953
AsíwájúVyacheslav Molotov
Arọ́pòGeorgy Malenkov
People's Commissar of Defence of the Soviet Union
In office
19 July 1941 – 25 February 1946
Alákóso ÀgbàHimself
AsíwájúSemyon Timoshenko
Minister of Defence of the Soviet Union
In office
25 February 1946 – 3 March 1947
Alákóso ÀgbàHimself
Arọ́pòNikolai Bulganin
Chairman of the State Defense Committee
In office
1941–1945
People's Commissar of Nationalities
In office
1917–1923
Alákóso ÀgbàVladimir Lenin
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí
Iosef Besarionis dze Jughashvili

(1878-12-18)18 Oṣù Kejìlá 1878
Gori, Tiflis Governorate, Russian Empire
Aláìsí5 March 1953(1953-03-05) (ọmọ ọdún 74)
Moscow, Russian SFSR, Soviet Union
Ọmọorílẹ̀-èdèSoviet
Georgian
Ẹgbẹ́ olóṣèlúCommunist Party of the Soviet Union
Signature


Ìtókasí

àtúnṣe
  1. "Joseph Stalin". Biography. 1953-03-05. Archived from the original on 2020-04-07. Retrieved 2020-04-04. 
  2. "Joseph Stalin - Biography, World War II, & Facts". Encyclopedia Britannica. 2020-03-27. Retrieved 2020-04-04.