Joseph Wayas
Joseph Wayas (tí wọ́n bí ní 21 May 1941 tó sì dágbére fáyé ní 30 November 2021[1]) fìgbà kan jẹ́ olórí ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà tí orílẹ́-èdè Nàìjíríà lásìkò tí Nàìjíríà gba òmìnira lọ́wọ́ ìjọba ológun(1979–1983).
Dr.Joseph Wayas | |
---|---|
President of the Senate of Nigeria | |
In office 1 October 1979 – 31 December 1983 | |
Asíwájú | Nwafor Orizu (1966) |
Arọ́pò | Iyorchia Ayu (1992) |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Obudu, Southern Region, British Nigeria (now Obudu, Cross River State, Nigeria | 21 Oṣù Kàrún 1941
Aláìsí | 30 November 2021 London, England, UK | (ọmọ ọdún 80)
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | PDP |
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀
àtúnṣeWọ́n bí Wayas ní Basang, Obudu, ìpínlẹ̀ Cross River ní 21st, May 1941, ó sì kẹ́kọ̀ọ́ jáde ní Dennis Memorial Grammar School, ní Onitsha. Ó lọ́ sí òkè-òkun níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ní Higher Tottenham Technical College, London, the West Bronwich College of Commerce, Science and Technology, Birmingham and Aston University, Birmingham. Nígbà tí ó padà dé orílẹ́-èdẹ̀ Nàìjíríà, ó ṣiṣẹ́ gẹ́gé bí i alámòójútó àti olùdarí láàárín ọdún 1960-1969 fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ilé-iṣé ní orílẹ́-èdè Nàìjíríà àti òkè-òkun.[2]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Joseph Wayas, former senate president, is dead
- ↑ "Senator Joseph Wayas President of the Senate Federal Republic of Nigeria (1979-1983)". Federal Ministry of Information and Communications, Nigeria. Archived from the original on 18 March 2012. Retrieved 28 February 2010. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)