Josephine Orji (ti a bi ni ọjọ Kẹjo oṣu Kẹrin ọdun 1979) jẹ ojogbon ninu agbara gbigbe ọmọ orilẹ-ede Naijiria . Ni ọjọ kerinla Oṣu Kẹsan ọdun 2016, o gba goolu ni ẹka + 86kg awọn obinrin ni olimpiki igba ooru àwọn akanda eda ni ọdun 2016 ni orile edè Brazil ṣaaju ki o to tẹsiwaju lati ṣeto igbasile agbaye ati ere tuntun nigbati o gbe 160kg ni ẹka kanna. [1] [2]

Josephine Orji
Òrọ̀ ẹni
Orúkọ àlàjẹ́Precious
Ọjọ́ìbí8 Oṣù Kẹrin 1979 (1979-04-08) (ọmọ ọdún 45)
Weight134 kg (295 lb)

Josephine n dagbasoke ife gidigidi fun ere ìdíje agbara gbigbe ni 2001 lẹhin abẹwo si ibi idaraya ni Owerri ati pe o tun gbiyanju ere idaraya naa fun igba akọkọ. Lẹhinna, o fi iṣẹ rẹ silẹ gẹgẹbi onimo ero kọnputa kan ni kafé kan o si bẹrẹ ikẹkọ rẹ lati ṣe idagbasoke iṣẹ-ṣiṣe ni ere-idaraya gẹgẹbi alagbara. [3]

Awọn itọkasi àtúnṣe