Josh Brolin

Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America

Josh James Brolin[1] ( /ˈbrln/; tí a bí ní ọjọ́ kejìlá oṣù kejì ọdún 1968)[2] jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà.

Josh Brolin
Brolin ní ọdún 2016
Ọjọ́ìbíJosh James Brolin
12 Oṣù Kejì 1968 (1968-02-12) (ọmọ ọdún 56)
Santa Monica, California, U.S.
Iṣẹ́Actor
Ìgbà iṣẹ́1984–present
WorksFull list
Olólùfẹ́
  • Alice Adair
    (m. 1988; div. 1994)
  • Diane Lane
    (m. 2004; div. 2013)
  • Kathryn Boyd (m. 2016)
Àwọn ọmọ4, including Eden
Parent(s)
ẸbíBarbra Streisand (stepmother)
AwardsFull list

Josh jẹ́ ọmọ James Brolin, ó sì di gbajúmọ̀ nígbà tí ó ṣeré nínú fíìmù The Goonies (1985). Lẹ́yìn òpò ọdún, Brolin tún ṣeré nínú fíìmù No Country for Old Men (2007). Ó gba àmì-ẹ̀yẹ Academy Award for Best Supporting Actor fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi Dan White nínú Milk (2008).

Brolin gbajúmọ̀ si nígbà tí ó kó ipa Thanos nínú àwọn fíìmù Marvel Cinematic Universe, àwọn bi Avengers: Infinity War (2018) àti Avengers: Endgame (2019), àti gẹ́gẹ́ bi Cable fún Deadpool 2 (2018). Àwọn fíìmù míràn tí ó ti ṣeré ni W. (2008), gẹ́gẹ́ bi Jonah Hex nínú fíìmù Jonah Hex (2010), True Grit (2010), Wall Street: Money Never Sleeps (2010), Men in Black 3 (2012) gẹ́gẹ́ bi Agent K, Oldboy (2013), Inherent Vice (2014), Everest (2015), Sicario (2015), Hail, Caesar! (2016), àti nínú Dune (2021).[3] Ní ọdún 2022, Brolin ṣeré nínú fíìmù Outer Range.

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Sign In". FamilySearch. Archived from the original  on May 17, 2022. Retrieved June 8, 2020.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. Screen World 2003, By John Willis, Barry Monush. Published by Hal Leonard Corporation, 2004. ISBN 1-55783-528-4, ISBN 978-1-55783-528-4
  3. Elliott, Warren (2022-04-13). "Josh Brolin Confirms His Dune 2 Return With Funny IMDb Story". ScreenRant (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on July 15, 2022. Retrieved 2022-07-15.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)