Josiah Sowande
Josiah Sobowale Sowande (ca 1858 -1936) tí a tún mọ sí Sobo Arobiodu jẹ́ akéwì ọmọ Yoruba àti Abeokuta, Ìpínlẹ̀ Ogun. Tí o jẹ́ olùkọ́we ti Ewì, ní ara ewì ti o jẹ èdè Yorùbá. [1]
Àwọn iṣẹ́ rẹ ni nípasẹ̀ ìdàgbàsókè ní Egba, àwọn iṣẹ ti Christian Missionary Society ní Egbaland àti àwọn orin Egba tí o gbajúmò, àwọn iṣẹ́ rẹ dálè lórí àwọn ẹlẹsin Egba ti o yipada sí olugbo akọkọ. [2]
Ìgbésí ayé rẹ
àtúnṣeA bí Sobowale ni Abeokuta, ca 1858. O kọ ẹkọ ìwé-kikọ ni ile-ẹkọ ikẹkọ CMS ṣugbọn ko pari ètò-ẹkọ rẹ, o gba iṣẹ gẹgẹ bi ẹṣọ túbú ni ijọba Ẹgba . O fi ipo ẹṣọ túbú rẹ silẹ láti bẹrẹ iṣẹ-àgbẹ̀ àti ìwé-kikọ. Láàárín ọdún 1905 sí 1934, àwọn iṣẹ́ rẹ̀ méjìlá ni wọ́n tẹ̀ jáde, àwọn kan lára ẹ̀rọ ìtẹ̀wé ìjọba Egba níbi tí àbúrò rẹ̀ ti ń ṣiṣẹ́. [3]
Sowande's ṣíṣe gẹ́gẹ́ bí àwọn Orin Arungbe, ó jẹ́ ewì tí àwọn Oro má lo.
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Nnodim, Rita (2006). "Configuring Audiences in Yorùbá Novels, Print and Media Poetry". Research in African Literatures 37 (3): 154–156. ISSN 0034-5210. http://www.jstor.org/stable/3821185.
- ↑ Okùnoyè, Oyèníyì (2010). "Ewì, Yorùbá Modernity, and the Public Space". Research in African Literatures 41 (4): 43–64. doi:10.2979/ral.2010.41.4.43. ISSN 0034-5210. http://www.jstor.org/stable/10.2979/ral.2010.41.4.43.
- ↑ Babalola, Adeboye (1985). Andrzejewski, B.W.. ed. Literatures in African languages : theoretical issues and sample surveys. Cambridge: Cambridge University Press. pp. 184–186. ISBN 0-521-25646-1. OCLC 10824164. https://www.worldcat.org/oclc/10824164.