Joslin Sharif Bipfubusa (ti a bi ni ọjọ kewa Oṣu Kẹwa Ọdun 1984) jẹ olukọni bọọlu lati orilẹ-ede Burundi. Oun na ni alabojuto Burundi lọwọlọwọ.

Iṣẹ iṣakoso

àtúnṣe

Bipfubusa ṣakoso Burundi lakoko idije Bangabandhu 2020, ni atẹle ise adaṣe ti o ti ṣakoso Aigle Noir ati ẹgbẹ Burundi labẹ-20 .

Awọn itọkasi

àtúnṣe