Pauline Joyce Meyer (née Hutchison; June 4, 1943) jẹ́ òǹkọ̀wé onígbàgbọ [1] onígbàgbọ ọmọ Amẹ́ríkà kan, agbọ̀rọ̀sọ̀ àti alága tí àwọn mínísítà Joyce Meyer. [2] Joyce àti ọkọ rẹ̀, Dave pèlú àwon ọmọdé merin tun ti dàgbà, gbé ní ìta st. Louis Missouri. Iṣẹ́-ìránṣẹ́ rẹ̀ wà ní ilé-iṣẹ́ nítòsí agbègbè St. Louis ti Fenton Missouri.

Joyce Meyer
Meyer speaking in 2015
Ọjọ́ ìbíPauline Joyce Hutchison
4 Oṣù Kẹfà 1943 (1943-06-04) (ọmọ ọdún 81)
St. Louis, Missouri, U.S.
Iṣẹ́Bible teacher, author, speaker
SpouseDave Meyer
Website
joycemeyer.org

Àwọn itọ́ka sí

àtúnṣe
  1. Hoxmeier, Christine (2019-10-30). "Which Joyce Meyer Book Should You Read First?". FaithWords. Retrieved 2023-02-22. 
  2. bizjournals.com. 2003-06-23 https://www.bizjournals.com/stlouis/stories/2003/06/23/story2.html. Retrieved 2023-02-22.  Missing or empty |title= (help)