Judith Susan Sheindlin ( née Blum;) ni abí ní ọjọ́ kọkànlélógún oṣù Kẹwàá, ọdún 1942. Ó jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Amẹ́ríkà, amòfin àti akọ̀wé. Sheindlin ti gba àmì-ẹ̀yẹ ìdáni lọ́lólá ti Day-time Emmy Award ní ọdún 1996.

Judy Sheindlin
Sheindlin ni 2012 Tribeca Film Festival
Ọjọ́ìbíJudith Susan Blum
21 Oṣù Kẹ̀wá 1942 (1942-10-21) (ọmọ ọdún 82)
New York City, New York, U.S.
Iléẹ̀kọ́ gíga
Iṣẹ́
Ìgbà iṣẹ́
  • 1965–1982 (attorney)
  • 1982–1996 (judge)
  • 1996–present (television personality)
Gbajúmọ̀ fúnJudge Judy
Net worth$500 million[1]
Olólùfẹ́Ronald Levy (m. 1964-1976)
Jerry Sheindlin (m. 1977-1990; m. 1991)
Àwọn ọmọ2

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe