Juice Wrld
Jarad Anthony Higgins (tí wọ́n bí ní 2, 1998, tí ó sì kú ní December 8, 2019) tí orúkọ ìnágijẹ rẹ̀ ń jẹ́ Juice Wrld, tí kíkọ sílẹ̀ rẹ̀ jẹ́ "Juice World ", jẹ́ ọmọọmọ olórin ilẹ̀ ìlú America, àti akọrin sílẹ̀. Ó jẹ́ aṣíwájú fún àwọn ọmọ ẹgbẹ́ "emo rap" àti "SoundCloud rap"
Juice Wrld | |
---|---|
Juice Wrld performing in July 2019 | |
Ọjọ́ìbí | Jarad Anthony Higgins Oṣù Kejìlá 2, 1998 Chicago, Illinois, U.S. |
Aláìsí | December 8, 2019 Oak Lawn, Illinois, U.S. | (ọmọ ọdún 21)
Cause of death | Acute oxycodone and codeine intoxication |
Resting place | Beverly Cemetery, Blue Island, Illinois |
Ẹ̀kọ́ | Homewood-Flossmoor High School |
Iṣẹ́ |
|
Alábàálòpọ̀ |
|
Àwọn olùbátan | Young Dolph (second cousin) |
Website | juicewrld999.com |
Àdàkọ:Infobox musician |
SoundCloud rap and genres, léyìí tí ó kó ọkàn àwọn ènìyàn ní àárín ọdún 2010. Orúkọ eré ìtàgé tí ó jẹ́ "ṣíṣe olórí ilé ayé" tí ó jẹ́ jáde láti inú eré sinimá àgbéléwò "crime thriller film Juice" (1992).
Àtòjọ àwọn orin rẹ̀
àtúnṣe- Àwo-orin láti studio
- Goodbye & Good Riddance (2018)
- Death Race for Love (2019)
- Legends Never Die (2020)
- Fighting Demons (2021)
- The Party Never Ends (2023)[3]
Àtòjọ fọ́nrán orin rẹ̀
àtúnṣeỌdún | Àkọ́lé | Ojúṣe | Ref. |
---|---|---|---|
2021 | Juice Wrld: Into the Abyss | Himself (archival footage) | [4] |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Starfire Is Juice Wrld's Ex-Girlfriend — And She's 'Not Okay' After The Rapper's Untimely Death". December 10, 2019. Archived from the original on June 2, 2021. Retrieved May 29, 2021. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "ally lotti's Instagram profile post". Instagram (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). November 4, 2018. Archived from the original on September 16, 2020. Retrieved April 23, 2020. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Fitzgerald, Trent (February 4, 2023). "Juice Wrld's Last Album in the Works, Lil Bibby Says". XXL. Retrieved February 5, 2023.
- ↑ "'Juice WRLD: Into the Abyss' Review: Gone-Too-Soon Rapper Tells His Story in Elegiac Documentary". November 13, 2021.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tags exist for a group named "lower-alpha", but no corresponding <references group="lower-alpha"/>
tag was found