Juliana Kakraba jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini ọjọ 29, óṣu December ni ọdun 1979[1].

Juliana Kakraba
Personal information
Ọjọ́ ìbí29 Oṣù Kejìlá 1979 (1979-12-29) (ọmọ ọdún 45)
Playing positionMidfielder
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
Ghatel Ladies
National team
Ghana women's national football team
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals).

Àṣeyọri

àtúnṣe
  • Juliana kopa ninu Cup FIFA awọn obinrin agbaye ti ọdun 1999[2].

Itọkasi

àtúnṣe
  1. https://www.eurosport.com/football/juliana-kakraba_prs414839/person.shtml
  2. https://ng.soccerway.com/players/juliana-kakraba/291409/