Jurelang Zedkaia
Jurelang Zedkaia (1950 - 2015) je oloselu ara awon Erekusu Marshall ati oloye ibe. Zedkaia je didiboyan bi the 5th Aare ikarun awon Erekusu Marshall ni October 26, 2009, leyin ti asaju re Litokwa Tomeing ti je yiyo kuro.[1]
Jurelang Zedkaia | |
---|---|
President Zedkaia (middle), flanked by Speaker Alvin Jacklick (L) and U.S. ambassador Martha Campbell. | |
President of the Marshall Islands | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 2 November 2009 | |
Asíwájú | Ruben Zackhras (Acting) |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 13 Oṣù Keje 1950 |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Àwọn Itokasi
àtúnṣe- ↑ "The Marshall Islands parliament has elected the Speaker, Jurelang Zedkaia, as its fifth President". RNZI (Islands Business). 2009-10-26. http://www.islandsbusiness.com/news/index_dynamic/containerNameToReplace=MiddleMiddle/focusModuleID=130/focusContentID=17163/tableName=mediaRelease/overideSkinName=newsArticle-full.tpl. Retrieved 2009-10-27.