Justine Bitagoye jẹ́ olùdarí eré, ònkọ̀tàn àti olùgbéréjáde ọmọ orílẹ̀-èdè Bùrúndì. Ó tún maá n ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bi agbéròyìn.