Kànga
Kànga jẹ́ ihò jíjìn kan tí a gbẹ́ sínú ilẹ̀ léte àti rí omi ilẹ̀ bu jáde fún Ìwúlò àti ìṣẹ̀mí ọmọnìyàn àti ẹranko. [1]
Ìrísí Kànga
àtúnṣeKànga ni ihò nla tí a fi búlọ́ọ́kù àti sìmẹ́ntì mọ yíká ihò tí a gbẹ́ náà. Lọ́pọ̀ ìgbà ni wọ́n ma ń fi ìfami tí a so okùn mọ́ nídìí fa omi jáde láti inú kànga náà.[2].[3]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Oram, Mr. Brian. "Well Water Problems Common Well Water Problems Water Testing- A Free Guide for Private Well Owners". Water Research Center. Retrieved 2019-12-31.
- ↑ "What to Know About Owning a Home with a Well". Water-Right. 2018-04-20. Retrieved 2019-12-31.
- ↑ "What Are the Differences between Well Water and Tap Water?". Water Filtration Systems. Archived from the original on 2019-12-31. Retrieved 2019-12-31.