Kẹ́místrì
Ìpògùn tí ṣe ẹ̀ka sáyẹ́nsì oníṣeẹ̀dá, jẹ́ ẹ̀kọ́ìwádìí ìkósínú, ìní àti ìwùwà ohun èlò.[1][2] Kẹ́místrì únsọ nípa àwọn átọ́mù àti ìbáraṣepọ̀ wọn pẹ̀lú àwọn átómù míràn, àgàgà pẹ̀lú àwọn ìní àwọn ìsopọ̀ kẹ́míkà. Kẹ́místrì tún úndálórí àwọn ìbáraṣepọ̀ láàrin àwọn átọ́mù (tàbí ọ̀pọ̀ àwọn átọ́mù) àti orísirísi irú okun (f.a. àwọn ìdaramọ́ra f fọ́tòkẹ́míkà, àwọn ìyípadà nínú ojúwà èlò, ìyàsọ́tọ̀ àwọn àdàlú, àwọn ìní pólímẹ̀r, at.b.b,lọ).
Kẹ́místrì únjẹ́ pípè nígbà míràn bíi "sáyẹ́nsì agbàrin" nítorípé ó so ìṣeẹ̀dá mọ́ àwọn sáyẹ́nsì onítaládánidá míràn bíi Jẹ́ọ́lọ́jì àti baolọ́jì.[3][4] Kẹ́místrì jẹ́ ẹ̀ka sáyẹ́nsì oníṣeẹ̀dá sùgbọ́n ó yàtọ̀ sí físíksì.[5]
Ìtumọ̀-ọ̀rọ̀
àtúnṣeÌtàn
àtúnṣeÀwọn òpó ìpògùn òdeòní
àtúnṣeÈlò
àtúnṣeÁtọ́mù
àtúnṣeÀkọ́bẹ̀rẹ̀
àtúnṣeÀdàpọ̀
àtúnṣeOunkókó
àtúnṣeHóró
àtúnṣeMólù àti iye àwọn ounkókó
àtúnṣeÀwon ìní
àtúnṣeÀwọn íónì àti iyọ̀
àtúnṣeÌjẹ́kíkan àti ìjẹ́ipìlẹ̀
àtúnṣeOjúìwà
àtúnṣeÌsopọ̀
àtúnṣeÌtúnṣe
àtúnṣeRẹ́dọ́ksì
àtúnṣeÀyèdídọ́gba
àtúnṣeOkun
àtúnṣeÀwọn òfin àpòpọ̀ògùn
àtúnṣeÀwọn ìtúnṣe àpòpọ̀ògùn ní àwọn òfin dájú tó ṣàkóso wọn, tí wọ́n ti dí òye àpilẹ̀sẹ̀ nínú ìpògùn. Díẹ̀ nínú wọn nìyí:
- Òfin Avogadro
- Òfin Beer-Lambert
- Òfin Boyle (1662, tó ṣe ìbáṣepọ̀ ìfúnpá àti ìkún)
- Òfin Charles (1787, tó ṣe ìbáṣepọ̀ ìkún àti ìgbónásí)
- Òfin ìtúsí Fick
- Òfin Gay-Lussac (1809, tó ṣe ìbáṣepọ̀ ìfúnpá àti ìgbónásí)
- Òpó Le Chatelier
- Òfin Henry
- òfin Hess
- Law of conservation of energy leads to the important concepts of equilibrium, thermodynamics, and kinetics.
- Law of conservation of mass continues to be conserved in isolated systems, even in modern physics. However, special relativity shows that due to mass-energy equivalence, whenever non-material "energy" (heat, light, kinetic energy) is removed from a non-isolated system, some mass will be lost with it. High energy losses result in loss of weighable amounts of mass, an important topic in nuclear chemistry.
- Law of definite composition, although in many systems (notably biomacromolecules and minerals) the ratios tend to require large numbers, and are frequently represented as a fraction.
- Law of multiple proportions
- Raoult's Law
Ẹ tún wo
àtúnṣeÀyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ "What is Chemistry?". Chemweb.ucc.ie. Archived from the original on 2018-10-03. Retrieved 2011-06-12.
- ↑ Chemistry. (n.d.). Merriam-Webster's Medical Dictionary. Retrieved August 19, 2007.
- ↑ Theodore L. Brown, H. Eugene Lemay, Bruce Edward Bursten, H. Lemay. Chemistry: The Central Science. Prentice Hall; 8 edition (1999). ISBN 0-13-010310-1. Pages 3-4.
- ↑ Chemistry is seen as occupying an intermediate position in a hierarchy of the sciences by "reductive level" between physics and biology. See Carsten Reinhardt. Chemical Sciences in the 20th Century: Bridging Boundaries. Wiley-VCH, 2001. ISBN 3-527-30271-9. Pages 1-2.
- ↑ Is chemistry a branch of physics? a paper by Mario Bunge[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]