Kabiru Gombe
Kabir Muhammad Haruna tí orúkọ gbajúgbajà rẹ̀ ń jẹ́ Kabiru Gombe jẹ́ onímọ̀ Islam àti oníwàásù. Láti December 2011[1] ni ó ti jẹ́ National Secretary General ti Jama'atu Izalatil Bid'ah wa Iqamatus Sunnah, èyí tí ó jẹ́ ẹgbẹ́ Salafiyyah tó gbòòrò jù lọ ní Nàìjíríà[2][3]
Iṣẹ́ rẹ̀
àtúnṣeMuhammad Kabir Haruna bẹ̀rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí i ọmọ-ẹgbé JIBWIS tí àwọn Hausa ń pè ní "Ƴan Agaji" lásìkò tó jẹ́ ọ̀dọ́; lẹ́yìn náà ni ó lọ sí Saudi Arabia láti lọ tẹ̀ síwájú nínú ẹ̀kọ́ ìmọ́ ẹ̀sìn Islam àti Kùránì. Muhammad Kabir Haruna ti jé Secretary General ti ẹgbẹ́ Izala láti December 2011.[4] Ó máa ń ṣe ọdún Ramadan Tafsir, bẹ́ẹ̀ sì ni ó máa ń lọ sí oríṣiríṣi Da'wah káàkiri Nigeria àti àwọn ìlú mìíràn bí i Niger, Cameroun, Chad, Ghana, àti United Kingdom.[5][6][7][8][9][10][11][12] Muhammad Kabir Haruna máa ń ṣe ìjìnlẹ̀ ìwásù lórí ọ̀rọ̀ àwọn obìnrin.[13] Lọ́wọ́lọ́wọ́, Muhammad Kabir Haruna ni national secretary JIBWIS[14]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Ochunu, Moses E. (25 January 2018). "Two Salafi Clerics Visit London". africasacountry.com. https://africasacountry.com/2018/01/why-salafi-clerics-london-visit-sparked-a-debate-on-modernity-and-morality-in-northern-nigeria. Retrieved 20 April 2020.
- ↑ Could Nigeria's Mainstream Salafis Hold Key to Countering Radicalization?, IPI Global Observatory, December 7, 2015.
- ↑ Day Izala regrouped in Kaduna, Daily Trust, December 31, 2011.
- ↑ Day Izala regrouped in Kaduna, Daily Trust, December 31, 2011.
- ↑ Auwal, Muhammad (2017-08-30). "An maka Malam Kabiru Gombe gaban kuliya manta sabo kan wani zargi". Legit.ng - Nigeria news. (in Èdè Hausa). Retrieved 2020-04-20.
- ↑ "'Sheikh Dahiru Bauchi ne yake kiran sunana a wa'azi'" (in ha). BBC News Hausa. 2017-11-27. https://www.bbc.com/hausa/labarai-42130508.
- ↑ "Mata sun fi maza bukatar wa'azi – Sheikh Kabiru Gombe" (in ha). BBC News Hausa. 2017-11-26. https://www.bbc.com/hausa/labarai-42130507.
- ↑ HausaTrust (2019-01-29). "Angano Sheikh Kabiru Gombe a Bakin Ruwa Yana Shan Soyayya". HausaTrust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-04-20.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ Muhammad, Musa (2019-02-22). "An Nemi Izala Ta Ja Kunnen Shaikh Kabiru Gombe". Leadership Hausa Newspapers (in Èdè Hausa). Retrieved 2020-04-20.
- ↑ "Two Salafi Clerics Visit London". africasacountry.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-04-20.
- ↑ Mustapha, Olusegun (2014-02-06). "Ba dabi'ar malaman Sunnah ba ne su ce wane yana wuta – Sheikh Kabiru Gombe". Aminiya (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-04-20.
- ↑ "Ana saka ran dawowar Sheikh Kabiru Gombe da Bala Lau gobe Talata daga Amurka". Dabo FM Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-04-29. Retrieved 2020-04-20.
- ↑ "Jawabin Kabiru Gombe kan matsayin musk a musulunci". BBC News Hausa (in Èdè Hausa). 2017-12-13. Retrieved 2020-04-24.
- ↑ arewa (2021-12-26). "Takaitaccen Tarihin Sheikh Kabiru Haruna Gombe". Arewa Times Hausa (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-03-20.