Kabiru Mijinyawa je olóṣèlú ọmọ orílè-èdè Nàìjíríà. Ó jẹ́ agbẹnusọ tẹ́lẹ̀ fún ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ìpínlẹ̀ Adamawa, tó ń ṣojú ẹkùn ìdìbò Gúúsù Yola . [1] [2] [3]

Awọn itọkasi

àtúnṣe