Kadiri Ikhana
Kadiri Ikhana (tí wọ́n bí lọ́jọ́ kọkànlélógbọ̀n oṣù Kejìlá ọdún 1951) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá fún ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù,Kano Pillars nígbà kan rí, tí ó wá di akọ́nimọ̀ọ́gbà bọ́ọ̀lù-àfẹségbá ọmọ Nigeria.
Personal information | |||
---|---|---|---|
Ọjọ́ ìbí | 31 Oṣù Kejìlá 1951[1] | ||
Ibi ọjọ́ibí | Ilorin, Nigeria[2] | ||
Ìga | 1.67m[2] | ||
Playing position | Midfielder[2] | ||
National team | |||
Nigeria | |||
Teams managed | |||
El-Kanemi Warriors | |||
BCC Lions | |||
Kwara United | |||
Sunshine Stars | |||
Sharks | |||
Giwa | |||
2003 | Enyimba | ||
2004 | Nigeria Olympic | ||
2008 | Kano Pillars | ||
2012 | Nigeria women | ||
2013 | Nasarawa United | ||
2014–2015 | Enyimba | ||
2016 | Shooting Stars | ||
2016–2017 | Kano Pillars | ||
† Appearances (Goals). |
Iṣẹ́ agbábọ́ọ̀lù
àtúnṣeIkhana gbá bọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá jẹun pẹlu ikọ̀ Bendel Insurance, tí wọ́n sìn gba ife-ẹ̀yẹ líìgì àgbábuta lọ́dún 1978 àti 1980.[3]
Ikhana wà lára ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Nigeria tí wọ́n ṣojú orílẹ̀-èdè náà láti gba ìdíje-amúnipegedé fún ìdíje ife àgbáyé FIFA tí wọ́n gbá díje nínú ìdíje Olympics lọ́dún 1980.[1] Ó wà lára ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Nigeria tí wọ́n gbé igbá orókè nínú ìdíje, 1980 African Cup of Nations.[3]
Iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí akọ́nimọ̀ọ́gbá
àtúnṣeIkhana ti ṣiṣẹ́ akọ́nimọ̀ọ́gbá fún oríṣiríṣi ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù àdání, lára wọn ni; El-Kanemi Warriors F.C., BCC Lions F.C., Kwara United F.C., Sunshine Stars F.C., Sharks F.C. àti Giwa F.C..[4]
Ikhana ni akọ́nimọ̀ọ́gbá ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Enyimba International F.C. lórílẹ̀-èdè tí wọ́n gba ife-ẹ̀yẹ, African Champions League lọ́dún 2003.[5] Ọdún yìí náà ni wọ́n yàn án gẹ́gẹ́ bí akọ́nimọ̀ọ́gbá tí ó dára jù lọ.[5] In 2004, he was manager of the Nigerian men's Olympic team.[6]
Lẹ́yìn náà ó ṣiṣẹ́ akọ́nimọ̀ọ́gbá fún ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Kano Pillars F.C., kí ó tó kọ̀wẹ́fipòsílẹ̀ lóṣù kaàrún ọdún 2008, pẹ̀lú ìbòsí ìwà àjẹbánu nínú àjọ eré-ìdárayá tí ó ké fún ìdí tí ó fi ṣe bẹ́ẹ̀.[5] He had led Kano Pillars to their first ever league title a day earlier.[7]
Wọ́n yàn án ní akọ́nimọ̀ọ́gbá àwọn ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-obìnrin tí orílẹ̀-èdè Nigeria lóṣù kẹrin ọdún 2012,[8] kí ó tó kọ̀wẹ́fipòsílẹ̀ lóṣù November, ọdún 2012.[9]
Ó ń ṣiṣẹ́ akọ́nimọ̀ọ́gbá fún ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Nasarawa United F.C. títí di oṣù November 2013 nígbà tí ó pinnu láti ṣíwọ́ iṣẹ́ eré-ìdárayá.[10] Ó tún padà sí ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Enyimba, tí ó sìn tún gba ife-ẹ̀yẹ líìgì àgbábuta kí ó tó tún dara pọ̀ mọ́ Shooting Stars S.C. lóṣù February ọdún 2016.[11] Ó tún padà sí ikọ̀ Kano Pillars lóṣù November ọdún 2016,[4][12] before being sacked in April 2017.[13]
Àwọn àṣeyọrí
àtúnṣeÀṣeyọrí gẹ́gẹ́ bí agbábọ́ọ̀lù
àtúnṣe- Pẹ̀lú Bendel Insurance
- Pẹ̀lú Nigeria
- African Cup of Nations – 1980[3]
Àṣeyọrí gẹ́gẹ́ bí akọ́nimọ̀ọ́gbá
àtúnṣe- Pẹ̀lú Enyimna
- Pẹ̀lú Kano Pillars
- Nigerian Premier League – 2008[7]
Àṣeyọrí aládàání
àtúnṣe- Akọ́nimọ̀ọ́gbá tí ó dára jù lọ lọ́dún 2003[5]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 Kadiri Ikhana - FIFA competition record
- ↑ 2.0 2.1 2.2 "Kadiri Ikhana". worldfootball.net. Retrieved 7 March 2019.
- ↑ 3.0 3.1 3.2 3.3 3.4 "Ikhana Impressed With Eaglets". Soccer Laduma. 1 August 2014. Archived from the original on 18 January 2017. Retrieved 15 January 2017.
- ↑ 4.0 4.1 Steve Dede (8 November 2016). "Veteran unveiled as head coach of Kano Pillars". Pulse. Archived from the original on 28 April 2017. Retrieved 15 January 2017.
- ↑ 5.0 5.1 5.2 5.3 5.4 Oluwashina Okeleji (27 May 2008). "Kano coach quits despite title". BBC Sport. Retrieved 15 July 2016.
- ↑ "Nigeria coach eyeing Athens". BBC Sport. 25 March 2004. Retrieved 15 January 2017.
- ↑ 7.0 7.1 "Kano Pillars win Nigerian league". BBC Sport. 26 May 2008. Retrieved 15 January 2017.
- ↑ Oluwashina Okeleji (19 April 2012). "Kadiri Ikhana appointed new coach of Nigeria women". BBC Sport. Retrieved 15 January 2017.
- ↑ Oluwashina Okeleji (13 November 2012). "Nigeria women coach Kadiri Ikhana resigns". BBC Sport. Retrieved 15 January 2017.
- ↑ Humphrey Njoku (1 November 2013). "No change of heart for Ikhana". Supersport. Retrieved 15 January 2017.
- ↑ 11.0 11.1 Shina Oludare (1 February 2016). "Kadiri Ikhana named Shooting Stars handler". Goal.com. Retrieved 15 January 2017.
- ↑ Samuel Ahmadu (7 November 2016). "Kadiri Ikhana returns as Kano Pillars coach". Goal.com. Retrieved 15 January 2017.
- ↑ Shina Oludare (23 April 2017). "Kadiri Ikhana sacked as Kano Pillars coach after Enugu Rangers defeat". Goal.com. Retrieved 24 April 2017.