Àdàkọ:Infobox Criminal organization

Kaduna Mafia (kì í ṣe ẹgbẹ́ ọ̀daràn) [1][2][3] bí kò ṣe ẹgbẹ́ àwọn olókowò, òṣìṣẹ́ ìjọba, àwọn onímọ̀ àti àwọn Ológun láti ihà àríwá Nigeria tí wọ́n ń gbé ní Kaduna tàbí tí wọ́n ń ṣòwò ní Kaduna, tí ó jẹ́ olú-ìlú àgbègbè apá àríwá nígbà náà ní ìparí sáà Ètò ìṣèlú eléèkìíní.

Ẹgbẹ́ náà fara jọ Sicilian Mafia, ẹgbẹ́ tí òun náà fi ìṣe jọ ẹ̀yà omertà, ethnicity. Wọ́n gbàgbọ́ pé àtakò ni ó ṣokùnfà dídá ẹgbẹ́ náà sílẹ̀ tí wọ́n sì wá di ìlú-mọ̀ọ́ká àti gbajúmọ̀ tí wọ́n lágbára láwùjọ nítorí ìbáṣepọ̀ tí wọ́n ní pẹ̀lú àwọn aláṣẹ òṣèlú, tí wọ́n gbé agbára ìlú ka àwọn oníṣòwò àdání, capitalism.

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Secrets of the Kaduna Mafia. Calabar, Nigeria: Panamora Books. 1987. https://searchworks.stanford.edu/view/2506054. 
  2. "Kaduna mafia: Metamorphosis of a power broker » Arewa Live » Tribune Online". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 18 November 2018. Retrieved 26 January 2020. 
  3. Jega, Mahmud (22 October 2016). "From Kaduna Mafia to Caliphate". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 26 January 2020.