Àdàkọ:Infobox museum

Kaduna Museum jẹ́ museum ní ìlu Kaduna, Nigeria. Wọ́n ṣí mùsíọ́mù náà ní ọdún 1975 ní ìfitọrẹ fún ìlú tí àwọn Northern People's Congress (NPC) tẹ́lẹ̀ rí tí ìjọba ìpínlẹ̀ ti àárín gbùngbùn Àríwá. Mùsíọ́mù Kaduna náà kún fún àkójọpọ̀ àwọn ohun pàtàkì tí ó ní ṣe pẹ̀lú kíkọ́lé, ohun ìṣẹ̀ǹbáyé àti àwọn oríṣiríṣi ohun iṣẹ́ ọnà ó sì ní àwọn ìkànnì iṣẹ́ ọ̀nà tí àwọn oníṣẹ́-ọnà lọ́kùnrin àti lóbìnrin lè máa wò láti kọ́ àwọn iṣẹ́-ọnà náà.[1]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe

Àdàkọ:Museums in Nigeria

Àdàkọ:Coord missing


Àdàkọ:Nigeria-museum-stub