Kajala Masanja (bíi ni ọjọ́ kẹjìlélógún oṣù keje ) jẹ́ òṣèré lórílẹ̀ èdè Tanzania.[1][2][3] Ó gbà àmì ẹ̀yẹ òṣèré bìnrin to dára jù lọ láti ọ̀dọ̀ East Television Award ní ọdún 2016[4]. Ó kópa nínú eré Kijiji Cha Tambua Haki pẹ̀lú Steven Kanumba.[5] O jẹ iyawo fun Faraji Chambo.[6][7]

Àṣàyàn eré rẹ̀

àtúnṣe
  • Kigodoro[8]
  • Jeraha la Moyo[9]
  • House Boy
  • Vita Baridi
  • House Girl & Boy
  • Dhuluma
  • Shortcut
  • Basilisa[10]
  • You Me and Him
  • Devils Kingdom

Àwọn Ìtọ́kàsi

àtúnṣe