Kalu Ikeagwu
Kalu Egbui Ikeagwu jẹ́ òṣèrékùnrin àti òǹkọ̀wé ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tó sì tún tan mọ́ orílẹ̀-èdè Britain.[2] Gẹ́gẹ́ bí òṣèrékùnrin tó jẹ́, ó ti gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ àmì-ẹ̀yẹ, wọ́n sì ti gbà á fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ àmì-ẹ̀yẹ pẹ̀lú fún àwọn iṣẹ́ rẹ̀.
Kalu Ikeagwu | |
---|---|
Kalu Ikeagwu at AMA Award 21 | |
Ọjọ́ìbí | Kalu Egbui Ikeagwu 18 May[1] England[1] |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigeria |
Iṣẹ́ | Actor |
Ìgbà iṣẹ́ | 2005–present |
Gbajúmọ̀ fún | 30 Days, Domino, Accident, Broken, Damage, Two Brides and a Baby |
Television | Tinsel, Domino, 168, Doctors' Quarters |
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀
àtúnṣeÌlú England ni wọ́n bí Kalu sí, àmọ́ ó kó lọ sí ilẹ̀ Nàìjíríà padà, nígba tó wà ní ọmọdún mẹ́sàn-án, nítorí ẹ̀rù àwọn òbí rẹ̀ pé ó lè gbàgbé àṣà àti ìṣe ilẹ̀ Igbo.[3][1] Ó ṣe ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ rẹ̀ ní England àti Zambia, kí ó tó lọ sí University of Nigeria láti lọ gba ẹ̀kọ́ nínú èdè Gẹ̀ẹ́sì.[3][4]
Iṣẹ́ tó yàn láàyò
àtúnṣeIkeagwu ṣe àfihàn àkọ́kọ́ ní ọdún 2005, nínú fíìmù àgbéléwò tí wọ́n máa ń ṣàfihàn lórí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán, tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Domino.[5] Ìsàfihàn akọ́kọ́ rẹ̀ lórí orí-ìtàgé jẹ́ Put Out The Houselights láti ọwọ́ Esiaba Ironsi. Ó ti tẹ̀síwájú láti lọ kópa nínú àwọn eré bí i "Major Lejoka Brown" nínú fíìmù Ola Rotimi, Our Husband Has Gone Mad Again àti gẹ́gẹ́ bí i "RIP" nínú fíìmù Esiaba Irobi, tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Hangmen Also Die. Ó sì tún ti kópa nínú àwọn fíìmù bí i For Real, 30 Days, The Wrong Woman, Distance Between, Between Two Worlds àti "Rapt In Éire". Ní orí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán, ó ti ṣàfihàn nínú àwọn fíìmù bí i Domino, 168 àti Doctors' Quarters (MNet Production ). Ó tún gbajúmọ̀ fún ẹ̀dá-ìtàn tó ṣe gẹ́gẹ́ bí i "Alahji Abubakar" nínú fíìmù Tinsel.[6]
Àtòjọ àwọn fíìmù rẹ̀
àtúnṣeFíìmù
àtúnṣe- Second Chances(2014) as Osagie
- Kafa Coh
- 30 Days
- The Distance Between
- Between Two Worlds
- Love my way
- The Wrong Woman
- Fragile Pain
- For Real
- Games Men Play
- Insecurity
- Crisis In Paradise
- War Without End
- My Precious Son
- Beneath Her Veil
- Damage
- Daniel's Destiny Plan
- Lionheart
- Pretty Angels
- The Lost Maiden
- Darkest Night
- Freedom Bank
- The Waiting Years
- Ocean Deep
- Count On Me
- Two Brides and a Baby
- Broken (2013)
- Accident
- Blue Flames (2014)
- Heaven's Hell (2015)
- O-Town (film) (2015)
- My rich boyfriend
- Three Thieves (2015)
- The Women (2018)
- Badamasi (2020)
Àtòjọ àwon fíìmù rẹ̀ lórí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán
àtúnṣe- Domino
- Doctors' Quarters
- 168
- Circle Of Three
- Super Story
- Tinsel
- Diiche
Ìgbóríyìn fún
àtúnṣeỌdún | Àmì-ẹ̀yẹ | Ìsọ̀í | Èsì | Ìtọ́ka |
---|---|---|---|---|
2014 | Best of Nollywood Awards | Best Supporting actor | Wọ́n pèé | [7] |
Golden Icons Academy Movie Awards | Best Actor | Wọ́n pèé | [8] | |
2013 | Golden Icons Academy Movie Awards | Wọ́n pèé | [9] | |
Africa Magic Viewers Choice Awards | Best Supporting Actor | Wọ́n pèé | [10] | |
2012 | Ghana Movie Awards | Best Actor (African Collaboration) | Wọ́n pèé | [11] |
2011 | Best of Nollywood Awards | Best Supporting Actor | Wọ́n pèé | [12] |
2006 | Africa Movie Academy Awards | Best Upcoming Actor | Wọ́n pèé |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 1.2 "Kalu Ikeagwu Biography". gistus.com. Retrieved 21 September 2014.
- ↑ "Exclusive Interview with Nollywood Star Actor, Kalu Ikeagwu". modernghana.com. Retrieved 21 September 2014.
- ↑ 3.0 3.1 "At age ten, I had lived in four different countries – Kalu Ikeagwu". vanguardngr.com. Retrieved 21 September 2014.
- ↑ "Girls pester me for marriage, but… – Kalu Ikeagwu". My Daily Newswatch. 10 August 2013. Archived from the original on 30 September 2013. Retrieved 30 September 2013. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedvan2
- ↑ "Kalu Ikeagwu: Top 5 movies of the talented 'Tinsel' actor". Pulse Nigeria. Chidumga Izuzu. Archived from the original on 20 July 2015. Retrieved 18 May 2015.
- ↑ "Best Of Nollywood Awards Nominees For The Year 2014 | Jaguda.com". Archived from the original on 3 July 2015. Retrieved 6 September 2015.
- ↑ "List of Nominees: Golden Icons Academy Movie Awards | Nollywood by Mindspace". Retrieved 6 September 2015.
- ↑ "Ini Edo, Ramsey Nouah, “Phone Swap”, Omawumi, “Contract”, Ireti Doyle & Hlomla Dandala Make the 2013 GIAMA Nominees List | See Who Else Made the List". BellaNaija. Retrieved 6 September 2015.
- ↑ "Genevieve Nnaji, OC Ukeje, Funke Akindele & Kalu Ikeagwu Make the 2013 Africa Magic Viewers’ Choice Awards Nominees List | First Photos from the Announcement in Lagos". BellaNaija. Retrieved 6 September 2015.
- ↑ "Ghana Movie Awards: List of Nominees". Archived from the original on 14 July 2014. Retrieved 6 September 2015.
- ↑ "The 2011 Best Of Nollywood (BON) Awards hosted by Ini Edo & Tee-A – Nominees List & “Best Kiss” Special Award". BellaNaija. Retrieved 6 September 2015.