Kamal Oyekunle Fagbemi (ọjọ́-ìbí April 28, 1963) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílè-èdè Nàìjíríà ati ọmọ ilé ìgbìmọ̀ asòfin kẹjọ tí ó ń sójú àgbègbè Oke-ogun ní ilé ìgbìmọ̀ asofin ìpínlẹ̀ Kwara . [1]

Awọn itọkasi

àtúnṣe