Kamounia
Kamounia, tí wọ́n máa ń kọ bí Kamouneya nígbà mìíràn,[1] jẹ́ ata ẹran ògúnfe àti ẹ̀dọ̀ tí a sè pẹ̀lú cumin.[2] Ó jẹ́ ara oúnjẹ Sudanese, Egyptian àti Tunisian.[3] Itan ọ̀yà náà máa ń jẹ́ lílò nígbà mìíràn gẹ́gẹ́ ohun èlò pàtàkì, àwọn ohun amọ́bẹ̀dùn náà sì máa ń di lílò nígbà mìíràn.[4] Nígbà mìíràn, ó máa ń di jíjẹ pẹ̀lú ìrẹsì ṣíṣè. Àfikún ohun èlò lè jẹ́ olú, gálíkì, òróró ólífì àti ewébẹ̀.
Kamounia | |
|
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Weiss, J.; Chirichigno, P. (2007). Egyptian Cooking English Edition. Bonechi. p. 79. ISBN 978-88-476-0706-4. https://books.google.com/books?id=1hXmCyYmMaoC&pg=PA79.
- ↑ Salloum, H. (2005). Arab Cooking on a Saskatchewan Homestead: Recipes and Recollections. Trade Books Based in Scholarship (TBS) Series. University of Regina Press. p. 55. ISBN 978-0-88977-182-6. https://books.google.com/books?id=iqHPLBxNA4kC&pg=PT55.
- ↑ DK Eyewitness Travel Guide: Tunisia. EYEWITNESS TRAVEL GUIDES. DK Publishing. 2016. p. 260. ISBN 978-1-4654-5090-6. https://books.google.com/books?id=2UROCgAAQBAJ&pg=PA260. Retrieved September 22, 2016.
- ↑ Tomkinson, M. (1972). Tunisia; a vacation guide. Scribner. p. 30. ISBN 978-0-684-12623-4. https://books.google.com/books?id=ORJPQYbryNAC&q=Kamounia.