Karayuki-san
Karayuki-san (唐行きさん)jẹ́ orúkọ tí àwọn ará ilè Japan tí wọn fún obìnrin tí wọn fí ipá jí gbé lọsí àwọn àgbègbè bí apá ìlà oòrùn Asia, Siberia, Russian , Australia, India láti lọ lò wọ́n gẹ́gẹ́ bí òsìsẹ̀ ìbálòpó láti yọ wọ́n kúrò nínú ìṣẹ́ láàrín ṣẹ́ńtúrì kọkàndíńlógún sí ogún ṣẹ́ńtúrì.