Karim Massimov
Karim Kajymqanuly Massimov (Àdàkọ:Lang-kk, Rọ́síà: Карим Кажимканович Масимов eya ibini Naiman, ibi ni odun 1965 ni Tselinograd, Kazakh SSR, USSR; to n je Astana loni ni Kazakhstan)[1] je Alakoso Agba ijoba orile-ede Kazakhstan lati 10 January 2007.[2]
Karim Massimov Кәрім Мәсімов Карим Масимов | |
---|---|
Alakoso Agba ile Kazakhstan | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 10 January 2007 | |
Ààrẹ | Nursultan Nazarbayev |
Deputy | Aslan Musin |
Asíwájú | Daniyal Akhmetov |
Deputy Prime Minister of Kazakhstan | |
In office 19 January 2006 – 10 January 2007 | |
Alákóso Àgbà | Daniyal Akhmetov |
Arọ́pò | Aslan Musin |
Minister of Economy and Budget Planning | |
Alákóso Àgbà | Daniyal Akhmetov |
Arọ́pò | Aslan Musin |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 15 Oṣù Kẹfà 1965 Tselinograd, Kazakh SSR, USSR (now Astana, Kazakhstan) |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Nur-Otan |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ Kazakhstan moves to name new PM United Press International
- ↑ Kazakhstan appoints new PM TVNZ