Karimot Olabisi Odebode
Karimot Olábísí Odébòdé jẹ́ alátìlẹ́yìn ẹ̀tọ́ ẹ̀kọ́, agbẹ́jọ́rò, akéwì, àti olùdásílẹ̀ Black Girl's Dream Initiative, ètò kan tí àwọn ọ̀dọ́ ń darí tó ṣe ìdáàbòbò láti dín àìṣóore àpapọ̀ tó wà láàárin àwọn obìnrin àti ọkùnrin.[1][2]
Karimot Odebode | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Ibadan, Nigeria |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Obafemi Awolowo University |
Iṣẹ́ | Education advocate |
Ní ọdún 2022, òun nikan ló jẹ́ ará Nàìjíríà tó wà lórí àkójọ àwọn "United Nations cohort of 17 Young Leaders for Sustainable Development Goals (SDGs)" tí Ajo Àgbáyé "United Nations" ṣe ìkede nígbà ìpàdé ìbẹ̀rẹ̀ ọdún kàádọrinléléje (77th session) ti Ìpàdé Gbogbogbò ti UN.[3][4]
Ó jẹ́ Olóyè Ọ̀dọ́ fún ONE Campaign ní Nàìjíríà, tó ń ṣe àgbékalẹ̀ ìjàkadì lòdì sí ìtálọ́sí.[5] Ní ọdún 2022, àjọ́ Ministry of Youth and Sports Oyo State sé àfihàn rẹ gẹgẹ bíi ọkàn nínú àwọn arábìnrín ọgọ́rùn-ún tó ní ipa pátáki nítorí iṣẹ́ àtìlẹ́yìn rẹ̀.[6]
Ó kọ àkójọpọ̀ ewi tó ní ojú ewé "156" pẹ̀lú ọgọ́rùn-ún ewi tó tẹ̀ jáde ní ọdún 2022 lábé àtìpó Noirledge Publishing, èyí tí ó fún àwọn obìnrin ní ohùn láti ṣàfihàn ìmọ̀lára wọn.[7][8]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Women participation in politics, leadership one way to develop Nigeria ─Karimot Odebode, lawyer, poet, activist". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-04-23. Retrieved 2023-11-18.
- ↑ Alumona, Kingsley (2023-08-05). "NGO trains Ibadan students in public speaking, hosts debate, essay contests". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-11-18.
- ↑ PositiveNaija (2022-09-23). "Karimot Olábísí Odébòdé Emerges In UN 2022 Cohort Of 17 Young Leaders For Sustainable Development Goals (SDGs)". PositiveNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-11-18.
- ↑ "Karimot Odebode". Office of the Secretary-General’s Envoy on Youth (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-11-18.
- ↑ "Meet the Global Citizen Fellowship Class of 2023: The Program Powered by BeyGOOD Kicks Off its Final Year". Global Citizen (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-08-24. Retrieved 2023-11-18.
- ↑ "Karimot Odebode". blog.mipad.org. Retrieved 2023-11-18.
- ↑ "Karimot Odebode releases debut poetry collection". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-03-06. Retrieved 2023-11-18.
- ↑ "Odebode launches poetry collection, charges women to break barriers around them". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-03-30. Retrieved 2023-11-18.