Karl Elbs
Karl Elbs, Ọjọ́ kẹtàlá Oṣù kẹsán Ọdún 1858 ní Alt-Breisach, Baden, Germany – Ọjọ́ kerìnlélógún Oṣù kẹjọ Ọdún 1933) jẹ́ onímọ̀ chemistry ọmọ orílẹ̀ èdè Jamaní. Ohun ní ó ṣèdá Elbs reaction fún ìṣètò anthracene. Ohun ló tún wà ní idi Elbs persulfate oxidation.
Àwọn ìtọkasí
àtúnṣe- E. J. Behrman, Bull. Hist. Chem., 30, 19-22(2005).