Karl Malone
Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America
Karl Anthony Malone (ọjọ́ìbí 24 Oṣù Keje, 1963) ni oníṣẹ́ agbábọ́ọ́lù alápẹ̀rẹ̀ ará Amẹ́ríkà tó ti fẹ̀yìntì. Wọ́n mọ̀ pẹ̀lú orúkọ ìnagijẹ "the Mailman", ó gbá ipò power forward. Ó gbá bọ́ọ́lù fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ́lù National Basketball Association (NBA) pẹ̀lú Utah Jazz àti Los Angeles Lakers.
Itokasi
àtúnṣe- ↑ Men's Tournament of the Americas – 1992, USA Basketball. Retrieved December 6, 2018.