Karlie Redd

Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America

Karlie Redd (née Lewis) tí a bí ní ọjọ́ kẹẹ̀dógún oṣù kẹrin, ọdún 1974, tí wọ́n sì sọ ní Keisha Lewis, [1] jẹ́ gbajúmọ̀ lórí ètò lọ́lọ́kan-ò-jọ̀kan lórì ẹ̀rọ amóhùnmáwòrán ní orílẹ̀-èdè Amerika. Ó tún jẹ́ òṣèré àti olórin.

Karlie Redd
Ọjọ́ìbíKarlie Lewis
Oṣù Kẹrin 15, 1974 (1974-04-15) (ọmọ ọdún 50)
New York City, New York, U.S.
Ẹ̀kọ́The Harlem School of the Arts
Iṣẹ́
  • Television personality
  • rapper
  • actress
  • model
Ìgbà iṣẹ́2001–present
Àwọn ọmọ1
Musical career
Irú orin
InstrumentsVocals
Websitekarlieredd.com

Atojo awon ere re àtúnṣe

Fiimu àtúnṣe

Year Title Role Notes
2001 Black Spring Break 2 as Keisha Lewis
2014 Top Five Rhonda as Karlie Lewis
2014 30 Days in Atlanta Kimberly as Karlie Lewis
2017 We Are Family Zantria as Karlie Lewis

Eto lori ero amohunmaworan àtúnṣe

Year Title Role Notes
2003 One on One Hairdresser, uncredited #Season 3 episode 22 "Phatheadz"
2010 Scream Queens Herself Contestant, credited as Karlie Lewis
2012–2020 Love & Hip Hop: Atlanta Main cast
2014 K. Michelle: My Life Guest
2015 Love & Hip Hop Live: The Wedding
2016–present Saints & Sinners Paige Morris Recurring cast member
2017 Black Ink Crew Herself Guest
2021–present Love & Hip Hop: Secrets Unlocked Main cast
VH1 Family Reunion: Love & Hip Hop Edition

Awon Itokasi àtúnṣe

  1. McCluskey, Audrey Thomas (2007). Frame by Frame III: A Filmography of the African Diasporan Image, 1994-2004. ISBN 978-0253348296. https://books.google.com/books?id=z5qmplifVDIC&q=keisha+karlie+lewis&pg=PA858.