Kashim Shettima

Igbakeji Aare orile-ede Nàìjíríà

Kashim Shettima (ọjọ́ ìbí; ọjọ́ kejì oṣù kẹsàn-án ọdún 1966) jẹ́ olóṣèlú tí ó jẹ́ igbá-kejì ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lọ́wọ́ lọ́wọ́,[1] òun ni ó jẹ́ Senato agbègbè Bornu Central láàrin ọdún 2019 sí 2023, ó sì tún jẹ́ Gómìnà Ipinle Borno láàrin ọdún 2011 sí 2019.

Kashim Shettima
Kashim Shettima, gómìna Ìpínlẹ̀ Borno tẹ́lẹ̀
Gomina Ipinle Borno
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
29 May 2011
AsíwájúAli Modu Sheriff
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí2 Oṣù Kẹ̀sán 1966 (1966-09-02) (ọmọ ọdún 58)
Ẹgbẹ́ olóṣèlúAll Progressive Congress (APC)



Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Majeed, Bakare (2023-05-29). "PROFILE: Bola Tinubu: The Kingmaker becomes Nigeria's President, 16th Leader". Premium Times Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-05-29. 

Àdàkọ:Àwọn Gómìnà Ìpínlẹ̀ Borno