Kate Henshaw
Kate Henshaw tí a tún mọ̀ sí Kate Henshaw-Nuttall ( wọ́n bi ní ọjọ́ kọkàndínlógún, oṣù keje, ọdún 1971)[1] jẹ́ gbajúmò eléré-orí ìtàgé.[2] Ní ọdún 2008, ó gbégbá orókè ní African Movie Academy Award fún ẹ̀dá ìtàn tí ó dára jù lọ nínú eré Stronger Than Pain.[3][4]
Kate Henshaw | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Kate Henshaw 19 Oṣù Keje 1971 Calabar, Nàìjíríà |
Iṣẹ́ | Actress |
Àwọn ọmọ | Gabrielle Nuttall |
Àwọn olùbátan | Andre Blaze (cousin) |
Ibere aye
àtúnṣeKate Henshaw jẹ́ ọmọ bíbí Ìpínlẹ̀ Cross River, òun sì ni àkọ́bí nínú ọmọ mẹ́rin tí òbí rẹ̀ bí. Ó lọ sí St Mary Private school ní Ajele, ní ìpínlè Èkó, lẹ́yìn èyí ni ó lọ sí Federal Government Girls College ní Calabar.[5]
Ó lo ọdún kan ni Ilé Ẹ̀kọ́ gíga, yunifásítì Calabar, níbi tí ó ti kọ́ ẹ̀kọ́ àtúnṣe, ó sì kó ìmọ̀ "Medical Microbiology" ni ilé ìwé Medical Lab Science , LUTH, ní ìpínlè Èkó.[6]
Henshaw tí ṣiṣẹ́ rí ní Bauchi State General Hospital, kí ó tó di eléré orí ìtàgé, ó ti ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí í àwòṣe ènìyàn, tí ó sì ṣe oríṣiríṣi ìpolówó lórí ẹ̀rọ amóhùnmáwòrán, ọ̀kan lára wọn ni "Shield" , èròjà òórùn tó dára.
Awon Fiimu
àtúnṣeÀmìn-ẹ̀yẹ
àtúnṣeOdun | Amin-eye | Abala | Fiimu | Abajade | Itokasi |
---|---|---|---|---|---|
2017 | Best of Nollywood Awards | Best Supporting Actress –English | The Women | Gbàá | [11] |
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "P.M. News". 2012: A Dramatic Year For Nigerian Artistes. 2012-12-28. Retrieved 2022-03-25.
- ↑ "Kate Henshaw: Biography and five interesting facts to sabi about di award winning actor - BBC News Pidgin". BBC News Pidgin. July 19, 2021. Retrieved May 29, 2022.
- ↑ "虎扑NBA-体育赛程". 虎扑NBA-体育赛程. 2018-01-30. Retrieved 2022-03-25.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ Ochuko, Rukevwe (2020-03-17). "Kate Henshaw Wins Best Actress In A Supporting Role At South Africa Rapid Lion Award". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News. Archived from the original on 2022-03-30. Retrieved 2022-03-25.
- ↑ Celebs, African (2019-07-19). "Nollywood Superstar Kate Henshaw is a year older today". Medium. Retrieved 2022-03-25.
- ↑ Husseini, Shaibu (2021-07-24). "Kate Henshaw @ 50: Garlands for timeless diva - Nigeria and World News". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News. Retrieved 2022-03-25.
- ↑ "'Aremu the Principal': Watch Kate Henshaw, Queen Nwokoye, Oyetoro Hafiz in trailer for new movie". Pulse Nigeria. Chidumga Izuzu. 20 May 2015. Retrieved 20 May 2015.
- ↑ "Chief Daddy | Netflix". www.netflix.com. Retrieved 13 November 2019.
- ↑ "New Money (2018 film)", Wikipedia, 24 October 2019, retrieved 13 November 2019
- ↑ "The Ghost and the House of Truth". THISDAYLIVE. 28 September 2019. Retrieved 13 November 2019.
- ↑ "BON Awards 2017: Kannywood’s Ali Nuhu receives Special Recognition Award". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-11-23. Retrieved 2021-10-07.