Kate Adebola Okikiolu (tí a bí ní ọdún 1965) jẹ́ onímọ̀ Máàsì, ọmọ orílẹ̀-èdè Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan.[2] Àwọn ènìyàn mọ̀ ọ́n fún iṣẹ́ rẹ̀ pẹ̀lú elliptic differential operators àti inner-city children.[3]

Kate Adebola Okikiolu
Ìbí1965 (ọmọ ọdún 58–59)
Ọmọ orílẹ̀-èdèBritish
PápáMathematical analysis
Elliptic operators
Ilé-ẹ̀kọ́Princeton University
UCSD
Johns Hopkins University
Ibi ẹ̀kọ́University of Cambridge
UCLA
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́síPresidential Early Career Award for Scientists and Engineers[1]

Ìpìlẹ̀ ayé àti Ẹ̀kọ́ rẹ̀

àtúnṣe

A bí Okikiolu ní 1965 ní England. Bàbá rẹ̀ ni George Olatokunbo Okikiolu, ó jẹ́ onímọ̀ Mátì tó gbajúmọ̀ lọ́pọ̀lọpọ̀ ní Nàìjíríà.[4] Ìyá rẹ̀ jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan tí ó ń kó Mátì ní ilé-ẹ̀kọ́ kan. Okikiolu gba àmì-ẹyẹ B.A. nínú ìmò Mátì ní Yunifásitì ti Cambridge ní ọdun 1987. Ní ọdun 1991, ó gba àmì-ẹ̀yẹ Ph.D. nínú ìmò Mátì ní Yunifásitì California ní Los Angeles.[5]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Àdàkọ:MacTutor
  2. "Katherine Okikiolu - Mathematicians of the African Diaspora". www.math.buffalo.edu. Retrieved 2020-06-10. 
  3. "Katherine Okikiolu - Biography". Maths History (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-10. 
  4. "Katherine Okikiolu - Biography". Maths History (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-11. 
  5. "Katherine Okikiolu - Mathematicians of the African Diaspora". www.math.buffalo.edu. Retrieved 2022-08-11.