Katherine Obiang
Katherine Obiang jé òsèrébìnrin ọmọ orílẹ-èdè Nàìjíríà àti Cameroon, agbóhùn-sáféfé àti olóòtú ètò amóhùnmáwòran. Lákòókó, ó sisé gégé bíi olóòtú ètò amóhùnmáwòrán fun Nigerian Television Authority (NTA) ni AM Express àti Nigeria Info 99.3FM.[1] Ó bèrè sí ní se eré, ó sì n kópa nínu sinimá àgbéléwò. Ó kópa nínu eré kan tí àkolé rè n jé The Women ní odún 2017. Ó gba àmì èye ní odún 2017 pèlú Kate Henshaw àti Obidi.[2]
Katherine Obiang | |
---|---|
Orílẹ̀-èdè | Cameroonian-Nigerian |
Iṣẹ́ | Actress On-air personality TV presenter |
Television | Am Express |
Àwọn ọmọ | 3 |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Katherine Obiang finds love in Nollywood". Vanguard (Nigeria) News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2013-01-18. Retrieved 2021-10-28. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Lekki wives: The dust in the diamond". Vanguard (Nigeria) News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2013-08-07. Retrieved 2021-10-28. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)