Kathryn Ryan Cordell Thornton (Ph.D.) (ojoibi August 17, 1952 in Montgomery, Alabama) je onimosayensi ati arinlofurufu tele fun NASA ara Amerika to ti lo wakati 975 ni ofurufu. Lowolowo ohun ni Igbakeji Olori Eko fun awon Eto Iparieko ni Ile-Eko Iseero ati Sayensi Alamulo ti University of Virginia.

Kathryn Ryan Cordell Thornton
NASA Astronaut
Orílẹ̀-èdèAmerican
IpòRetired
Ìbí17 Oṣù Kẹjọ 1952 (1952-08-17) (ọmọ ọdún 72)
Montgomery, Alabama
Iṣẹ́ mírànPhysicist
Àkókò ní òfurufú40d 15h 14m
Ìṣàyàn1984 NASA Group
ÌránlọṣeSTS-33, STS-49, STS-61, STS-73
Àmìyẹ́sí ìránlọṣe