Kaylah Oniwo
Kaylah Oniwo(bíi ni ọjọ́ kẹji lélógún oṣù kìíní) je agbóhùnsáfẹ́fẹ́, osere ni Nàìjíríà. Òun ni atọkun ètò The Road Show àti Catwalk with Kaylah lóri Cool Fm.[1]
Kaylah Oniwo | |
---|---|
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀
àtúnṣeWọ́n bí Kaylah ni oọjọ́ kẹji lélógún oṣù kìíní sì Nàìjíríà. Bàbá rẹ̀ jẹ́ ìkan láàrin àwọn adarí àwọn ológun orí omi, ìyá rẹ sì jẹ ẹni tí ó rán aṣọ.[2] Ó gboyè ninu ẹ̀kọ́ ìmò ifowopamọ ní ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Bowen University. Ó tún gboyè nínú eré ṣiṣẹ́, ijó àti ère orí ìtàgé láti ọ̀dọ̀ Lufodo Academy of Performing Arts.
Iṣẹ́
àtúnṣeÓ ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi alágbátà ni ibi it wọn tí tá aṣọ ni ọdún 2005. Ó ti ṣe atọkun ètò bii Campus Square, Youth Scene fún Radio Unity Nàìjíríà Fm. Ó darapọ̀ mọ́ CoolFm ni odun 2010. Ó ṣe atọkun ètò The Road Show tí ó má ń bẹẹ rẹ láti àgó mẹta ìrọ̀lẹ́ di àgó méje ìrọ̀lẹ́. Ó tún má ń ṣe atọkun fún ètò rẹ, Catwalk with Kaylah, níbi tí ó tí má sọ̀rọ̀ nípa oge ṣíṣe. Kaylah jẹ́ aṣojú fún ilé iṣẹ́ Makari. Òun àti àwọn obìnrin mefa jọ kópa nínú ètò Agbára àwọn méje tí Bland2Glam gbé kalẹ̀. Kaylah tí ṣe olootu fún àwọn ayẹyẹ bíi:
Ẹ̀bùn
àtúnṣeYear | Award | Category | Result | |
---|---|---|---|---|
2012 | ELOY Awards | Best Female on-Air Personality | Gbàá | [2] |
2014 | Nigerian Broadcasters Merit Awards | Sexiest On-Air Personality | Wọ́n pèé | [4] |
Outstanding Radio Program Presenter (s) (Drivetime 4pm-8pm) | Wọ́n pèé | [4] | ||
2018 | City People Entertainment Awards | On-Air Personality Of the Year | Wọ́n pèé | [5] |
2019 | On-Air Personality Of the Year | Wọ́n pèé |
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 1.2 1.3 CoolFM, StayBusy Tech For. "Cool FM Nigeria | #1 Hit Music Station". CoolFM (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-05-09.
- ↑ 2.0 2.1 "KAYLAH ONIWO: My life as an On-Air Personality". Latest Nigeria News, Nigerian Newspapers, Politics (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-03-03. Retrieved 2020-05-09.
- ↑ "The gorgeous OAP with a distinct voice, Kaylah Oniwo". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-03-07. Archived from the original on 2020-09-27. Retrieved 2020-05-09.
- ↑ 4.0 4.1 "Nominees For Nigerian Broadcasters Merit Awards (NBMA) 2014". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2014-10-03. Retrieved 2020-05-09.
- ↑ Reporter (2018-10-17). "#CPMA2018: City People Music Awards Nominees' List Out". City People Magazine (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-05-09.