Káyọ̀dé Ẹ̀ṣọ́

(Àtúnjúwe láti Kayode Eso)

Bobakayode Eso (18 September, 1925 - 16 November, 2012)A bí Justice Kayọde Èsó ní ọjọ́ kọkànlá oṣù kẹ́sàn-án ọdún 1925. Ó lọ sí Holy Trinity School Iléṣà láàrin 1933-1939 àti Trinity College, Durban láàrin 1949-1953. Wọ́n pè é sí Bar ní Lincoln Inn, London ní 1954. Òun ni Chief Judge àkọ́kọ́ ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ní Western Court of Appeal ipimle naa. Wọ́n yàn án ní Justice Supreme Court, Lagos ní 1978. Ó ti fẹ̀yìn tì báyìí.

Káyọ̀dé Ẹ̀ṣọ́