Kayode Fayemi
Olóṣèlú
Kayode Fayemi, (ojoibi February 9, 1965) ni Gomina Ipinle Ekiti lowolowo lati 15 October 2010. O wa lati Isan-Ekiti ni Agbegbe Ijoba Ibile Oye ni Ipinle Ekiti, Nigeria.
Kayode Fayemi | |
---|---|
Gomina Ipinle Ekiti | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 15 October 2010 | |
Asíwájú | Olusegun Oni |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 9 Oṣù Kejì 1965 |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |