Kehinde Bankole
òṣèré orí ìtàgé ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà
Kehinde Bankole jẹ́ òṣèré ará Nàìjíríà, àwòkọ́ṣe àti olùgbàléjò. Ó bẹ̀rẹ̀ssí ní kópa nínú ìṣe tíátà nínu eré superstory, tí Wálé Adénúgà.[1] [2] Ó jẹ́ ọmọ kẹrin nínú ìdílé èyaàn mẹ́fà. Ó ní ìbejì, tí ó má ń kópa nínú eré ní ẹ̀kànkàn.
Kehinde Bankole | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Kehinde Bankole 27 Oṣù Kẹta 1985 Ogun State, Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹ̀kọ́ | Mass Communication, Olabisi Onabanjo University |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Olabisi Onabanjo University |
Iṣẹ́ | Actress, model, TV host |
Ìgbà iṣẹ́ | 2003–present |
Awards | revelation of the year award at 2009 Best of Nollywood Awards |
Ìgbésí ayé rẹ̀
àtúnṣeÓ jẹ́ ọmọ kẹrin nínú ìdílé èyaàn mẹ́fà . Ó ní arábìnrin ìbejì kan tí ó má ń ṣeré lẹ́kọ̀ọ̀kan. Ó kàwé ní Tunwase Nursery and Primary School, Ikeja. Ó kẹ́kọ̀ọ́ ìbáraenisọ̀rọ̀ ọ̀pọ̀ ní Ilé-ẹ̀kọ́ gíga Olabisi Onabanjo ṣùgbọ́n ó sinmi lati dojú kọ iṣẹ́ àwòṣe rẹ̀ ní ọdún 2004.[3]
Àtòjọ àwọn fíìmù rẹ̀
àtúnṣeỌdún | Iṣẹ́ | Ojúṣe | Ọ̀rọ̀ |
---|---|---|---|
2011 | Perfect Church | Film | |
Two Brides and a Baby | Pewa | ||
2012 | The Meeting | Kikelomo | |
2013 | Awakening | Zainab | |
Façade | |||
2014 | Render to Caesar | ||
October 1 | Miss Tawa | ||
2015–present | Desperate Housewives Africa | Kiki Obi | Television |
2016–present | Dinner | ||
2018 | Grace | ||
No Budget | |||
2018 | Bachelor's Eve | ||
2019 | The Set Up | ||
2020 | Dear Affy | Affy | |
Mama Drama | Kemi | ||
Finding Hubby | |||
2021 | Love Castle | ||
2021 | Country Hard | ||
2022 | Blood Sisters | Yinka Ademola | |
2022 | Sistá | Sistá | |
2023 | Kizazi Moto: Generation Fire | Moremi (voice) | Episode: "Moremi" |
Àmì-ẹ̀yẹ àti yiyan fún àmì-ẹ̀yẹ
àtúnṣeỌdún | Ayẹyẹ | Ẹ̀bùn | Fíìmù | Èsì | Ìtọ́ka |
---|---|---|---|---|---|
2014 | ELOY Awards | TV Actress of the Year (Super Story) | N/A | Wọ́n pèé | [4] |
2020 | 2020 Best of Nollywood Awards | Best Actress in a Lead role –English | Dear Affy | Wọ́n pèé | [5] |
2021 | Abuja International Film Festival | Outstanding Female Actor | Love Castle | Wọ́n pèé | [6] |
2022 | Africa Magic Viewers' Choice Awards | Best Actress in A Drama | Dear Affy | Iṣẹ́ ń lọ lórí ẹ̀ | [5] |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Yinka, Ade (14 April 2021). "Actress, Kehinde Bankole reveals why she ignores her fans". Kemi Filani News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 15 March 2022.
- ↑ "Acting involves brainwork, not only good looks — Kehinde Bankole". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 15 May 2022. Retrieved 19 July 2022.
- ↑ https://www.manpower.com.ng/people/15982/kehinde-bankole
- ↑ "Seyi Shay, Toke Makinwa, Mo’Cheddah, DJ Cuppy, Others Nominated". Pulse Nigeria. Chinedu Adiele. Archived from the original on 3 July 2017. Retrieved 20 October 2014.
- ↑ 5.0 5.1 "Behold hot steppers and winners at BON awards 2020". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 12 December 2020. Retrieved 11 October 2021.
- ↑ "2022 Africa Magic Awards Nominees don land- See who dey list". BBC News Pidgin. https://www.bbc.com/pidgin/tori-60818021.