Kehinde Smith jẹ́ Òǹtajà tó ní àṣeyọrí lórí okòwò rẹ̀, bákan náà ni ó jé olùdarí ati Olùdásílẹ̀ beauty Brand tí wọn ń pè ní MY EXTENSIONZ: tí ó dá sílẹ̀ ní orílé-èdè United Atare láti bí ọdún mẹ́fà sẹyìn, àti ní orílé èdè Nàìjíríà. Kehinde Smith tẹ̀síwájú láti tún bẹrẹ fẹ́ My Extension lójú sí ní orílé èdè Nàìjíríà nípa fífi Irun àti ṣíṣe Èẹkánná àti kí á ló Laser láti fí jékí ẹyin mọ (laser teeth whitening centre). Ọ jé gbajúmò níbi kí bá tá Virgin hair àti 3D Nini Lashes àti àwọn ohun oge ṣíṣe miiran; My Extension tí wá lára àwọn tí ó tayọ níbi ká ṣe Irun àti ta àwọn ohun tó jẹ mọ oge ṣíṣe. Lára ṣíṣe ìwádìí lórí Irun oge ṣíṣe, ọ wá lára àwọn tí wón Yan fún Future Awards Africa for Beauty ni ọdún 2016. Ní ọdún 2017, Kehinde mú ohun tí ó fẹràn gege bí iṣẹ beauty and lifestyle Influencer. Ní bí kí a mú iṣẹ ni òkùnkùndùn, àti ìṣe àṣẹkára ni ọ jẹ́ kí ó ní àwọn tí 70,000 followers lórí ẹrọ Instagram kí oṣù meje ó tó pé orúkọ rẹ̀ sí ń jẹ́ "Your Melanin Godmother". Páge rẹ lórí Instagram jẹ́ kí ó ní àpèjúwe tí ó yanranti tí ó jé kí àwọn àwòrán rẹ gúnrégé, èyí tí ó ń gbe àwọ dúdú ga tí ó sí jẹ́ òun ìwúrí fún àwọn obìnrin yòókù láti ṣé òun tí ó ń ṣe. Bákanáà ní ọ tí gbà àwọn àmì ìdámò àti ìfọwọ́sí láti àwọn ilé iṣé òkèrè bí Revolve, Oh Poly, Sinmi àti bẹẹ bẹẹ lọ. Ó Pinnj lati fi àwọn ipa re gẹgẹ bí Brand Ambassador tí Revolve clothings láti fi tún bọ́ ṣe alagbawi fun onírúurú ilé iṣé yálà lókè òkun tàbí ní ilẹ Nàìjíríà.

[1]

  1. "Kehinde Smith's schedule for Social Media Week Lagos". Social Media Week Lagos. 2018-03-02. Retrieved 2022-05-23.