Kel Ahaggar (Berber: ⴾⵍ ⵂⴴⵔ) (trans: "àwọn ènìyàn Ahaggar") ni àwọn ẹ̀yà Tuareg kan tí wọ́n gbé ní àwọn òkè Hoggar (àwọn òkè Ahaggar) ní orílẹ̀ èdè Algeria. Àwọn apìtàn gbàgbọ́ pé matriarch Tin Hinan ni ó dá ẹ̀yà náà kalẹ̀, ibojì rẹ̀ wà ní Abalessa. Wọ́n dá kalẹ̀ láàrin ọdún 1750. Ẹ̀yà náà ni agbára lọ́wọ́ ara wọn, kí ó tó di ọdún 1977, nígbà tí ìjọba Algeria gba agbára lọ́wọ́ wọn.

Kel Ahaggar
Ihaggarren
ⴾⵍ ⵂⴴⵔ

1750–1977
Flag of ⴾⵍ ⵂⴴⵔ
Àsìá
Àwòrán Kel Ahaggar Tuareg
Àwòrán Kel Ahaggar Tuareg
StatusÀdàkọ:Infobox country/status text
OlùìlúHoggar Mountains, Algeria
Àwọn èdè tówọ́pọ̀Berber
Ẹ̀sìn
Islam
ÌjọbaTribal Confederacy
Amenokal 
Ìtàn 
• Kel Ahaggar established
1750
• Under French suzerainty
1903
• not recognized by independent Algeria
1962
• terminated by Algerian Government
1977
Àdàkọ:Infobox country/formernext
Today part ofAlgeria

Èdè ẹ̀yà náà ni Tahaggart.