Ken Watanabe
Ken Watanabe (渡辺 謙, tí a bí ní ọjọ́ kanlélógún oṣù Kẹ̀wá ọdún 1959) jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè Japan. Ó gbajúmọ̀ láàrin àwọn elédè Gẹ̀ẹ́sì fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí General Tadamichi Kuribayashi nínú eré Letters from Iwo Jima àti gẹ́gẹ́ bi Lord Katsumoto Moritsugu nínú eré The Last Samurai, èyí tí ó mú kí wọ́n yán kún àwọn tí ó tó sí Academy Award for Best Supporting Actor. Àwọn àmì ẹyẹ míràn tí ó ti gbà ni Japan Academy Film Prize for Best Actor lẹ́mejì, àkọ́kọ́ ní ọdún 2007 fún Memories of Tomorrow àti èkejì ní ọdún 2010 fún Shizumanu Taiyō. Ọ̀pọ̀ tún mọ́ fún ipa rẹ̀ nínú eré Christopher Nolan pẹ̀lú àkọ́lé Batman Begins àti Inception, pẹ̀lú pẹ̀lú Memoirs of a Geisha, àti Pokémon Detective Pikachu.
Ken Watanabe | |
---|---|
Watanabe ní ibi ìsí Memories of Tomorrow | |
Ọjọ́ìbí | 21 Oṣù Kẹ̀wá 1959 Hirokami, Niigata, Japan |
Iṣẹ́ | Actor |
Ìgbà iṣẹ́ | 1979Àdàkọ:Endashpresent |
Olólùfẹ́ |
|
Àwọn ọmọ |
|
Ní ọdún 2014, ó ṣeré nínú eré Godzilla gẹ́gẹ́ bi Dókítà Ishiro Serizawa àti nínú Godzilla: King of the Monsters. Ní ọdún 2022, ó ṣeré nínú eré HBO Max tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Tokyo Vice.