Otolorin Kehinde Peter, tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ Kenny Blaq, jẹ́ olórin àti apanilẹ́rìn-ín orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1][2][3] Ó ṣeré níbi ayẹyẹ kejì ti Naija Independence [4][5] àti ayẹyẹ àṣekágbá ti Africa Magic.[6]

Kenny Blaq
Orúkọ àbísọOtolorin Kehinde Peter
Ìbí30th of September, 1992
Ajẹ́ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
Ibiìtakùnkennyblaq.tv

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀

àtúnṣe

kenny Blaq kàwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ àti girama ní Ejigbo, ní Ìpínlẹ̀ Èkó. Ó ní láti kúrò ní SS3 láti lọ sí ilẹ́-ẹ̀kọ́ mìíràn nígbà tí àwọn òbí rẹ̀ ò lè san owó ilé-ìwé rẹ̀ mọ́.[7]

Ó kẹ́kọ̀ọ́, ó sì ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí agbéròyìn sáfẹ́fẹ́ ní ilé-ìwé FRCN ní ìpínlẹ̀ Èkó.[8][9]

Iṣẹ́ rè

àtúnṣe

Blaq bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ apanilẹ́rìn-ín rẹ̀ ní ọdún 2008,[10] ó sì ti ṣeré lọ́pọ̀lọpọ̀ ayẹyẹ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti lókè òkun bí i I laff pẹ̀lú Mc Abbey, Gbenga Adeyinka (Laffmattaz), Ali Baba's & Fina - Ali , Mc Amana's (DiSpeakable Me), Cool FM Praise JAM, DAREY's Love Like A Movie, AY LIVE, BasketMouth's (Lord of the Ribs),[11] Africa Laughs (Uganda), SEKA Live (Rwanda) ECOFEST (Sierra Leone) àti BENIN GLO LAFFTA FEST (Nigeria)[12]

Ayẹyẹ apanilẹ́rìn-ín tó jẹ́ tirẹ̀ gan-an tó pè ní The Oxymoron Of Kennyblaq gba àmì-ẹ̀yẹ eré apanilẹ́rìn-ín tó dára jù lọ ní ọdún 2017 àti 2018.[13][14][15][16][17]

Àtọ̀jọ àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀

àtúnṣe
Year Awards Categories
2015 Naija FM Comedy Awards[18] Upcoming Comedian of the Year
2016 MEAMA Awards[18] Best Comedy Act, Nigeria
Naija FM Comedy Awards[13] Best Comedian of The Year
2017 The Future Awards Africa[19][20] Comedy
Naija FM Comedy Awards[13] Best Comedy Show

Comedian of The Year

2018 Naija FM Comedy Awards[14] Comedian of the Year
Best Comedy Show
Most Fashionable Comedian
2019 Naija FM Comedy Awards Most Fashionable Comedian
MAYA Awards Comedian of The Year (Stand Up)
2021 Humor Awards Best Music Comedian

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Olonilua, Ademola (6 January 2018). "Finding true love is really tough as a star –Kenny Blaq". Retrieved 1 January 2019. 
  2. "Choosing between music, comedy was hard – Kenny Blaq". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-11-30. Retrieved 2022-12-03. 
  3. "Nigerian comedians can sell out 02 arena - Kenny Blaq The Nation Newspaper" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-03-14. Retrieved 2022-12-03. 
  4. Nwafor (2022-10-11). "Kaffy, Denrele, Kenny Blaq, others grace Tobems media unlock naija". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-12-03. 
  5. "Kenny Blaq, Toyin Lawani, others headline Tobems media's Unlock Naija - Businessday NG". businessday.ng. Retrieved 2022-12-03. 
  6. Online, Tribune (2020-08-01). "Kenny Blaq and Laolu Gbenjo to perform at Africa Magic owambe finale". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-12-03. 
  7. "Before Stardom With... Kenny Blaq". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-01-31. Retrieved 2022-12-03. 
  8. "Comedy's next big thing in Nigeria, Kenny Blaq". pulse.ng. 20 August 2018. Retrieved 1 January 2019. 
  9. "Meet Kenny Blaq: Biography, Age, Education, Family, And Career". koko.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-10-13. Archived from the original on 2022-10-13. Retrieved 2022-12-03. 
  10. "About Him". Archived from the original on 1 January 2019. Retrieved 1 January 2019. 
  11. "Comedian delivers an incredible night of comedy in London". pulse.ng. 2 October 2018. Retrieved 1 January 2019. 
  12. "Acapella, Kenny Blaq on fire at Benin Glo Laffta Fest". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-06-25. Retrieved 2022-12-03. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  13. 13.0 13.1 13.2 Augoye, Jayne (20 June 2018). "Kenny Blaq returns with 'Oxymoron II' comedy show". Retrieved 1 January 2019. 
  14. 14.0 14.1 "Sola Sobowale, Kenny Blaq, other win big at Naija FM Comedy Awards". 10 November 2018. Retrieved 1 January 2019. 
  15. Online, Tribune (2019-06-21). "Music meets comedy: The Oxymoron of Kenny Blaq billed for ‘Third term’". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-12-03. 
  16. "The Oxymoron of Kenny Blaq – THISDAYLIVE". www.thisdaylive.com. Retrieved 2022-12-03. 
  17. "Kenny Blaq returns with second edition of 'Oxymoron' comedy show". TheCable Lifestyle (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-06-19. Retrieved 2022-12-03. 
  18. 18.0 18.1 "Kenny Blaq Signed As Tromville's Brand Ambassador". 19 February 2018. Archived from the original on 1 January 2019. Retrieved 1 January 2019. 
  19. "The Future Awards Africa 2017: Full List Of Winners". 10 December 2017. Archived from the original on 1 January 2019. Retrieved 1 January 2019. 
  20. "TFAA 2017 Winners List".