Kerry Washington
Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America
Kerry Marisa Washington[1] (ọjọ́-ìbí January 31, 1977)[2][3][4] jẹ́ olóòtú, olùdarí àti Òṣeré sinimá àgbéléwò ọmọ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà. Ó di gbajúmọ́ látàrí ipa tó kó gẹ́gẹ́ bí ẹ̀dá-ìtàn Olivia Pope nínú eré orí ẹ̀rọ tẹlifíṣàn kan tí àkọlé rẹ̀ ń jẹ́ Scandal (2012–2018).[5]
Kerry Washington | |
---|---|
Washington in 2013 | |
Ọjọ́ìbí | Kerry Marisa Washington 31 Oṣù Kínní 1977 New York City, U.S. |
Iléẹ̀kọ́ gíga | George Washington University |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 1994–present |
Olólùfẹ́ | Nnamdi Asomugha (m. 2013) |
Àwọn ọmọ | 2 |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Finn, Natalie (July 3, 2013). "Kerry Washington & Nnamdi Asomugha's Secret Wedding—See Their Marriage Certificate!". E! News. Retrieved September 26, 2013.
- ↑ "On This Day". The New York Times. January 31, 2009. Archived from the original on March 4, 2016. https://web.archive.org/web/20160304195556/http://www.nytimes.com/learning/general/onthisday/20090131.html. Retrieved August 6, 2009.
- ↑ Finn, Natalie (May 2, 2014). "Kerry Washington Is a Mom! Check Out Baby Isabelle Amarachi Asomugha's Birth Certificate". E! News. Archived from the original on April 26, 2016. Retrieved May 2, 2016. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) Sidebar: Certificate of Live Birth: Isabelle Amarachi Asomugha (County of Los Angeles Department of Public Health). Gives Kerry Washington birth date. Archived from the original on May 2, 2016. - ↑ Note: FilmReference.com states "Born January 5, 1977 (some sources cite 1975)…." at "Kerry Washington Biography (1977?- )". Archived from the original on March 3, 2016. Retrieved May 2, 2016. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Bricker, Tierney (May 13, 2011). "ABC picks up 'Charlie's Angels,' 'Good Christian Belles' and ten more". Archived from the original on May 5, 2012. Retrieved October 1, 2012. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)
Ìkìlọ̀: Bọ́tìnì ìtò àkọ́kọ́ṣe "Washington, Kerry" dípò Bọ́tìnì ìtò àkọ́kọ́ṣe "Washington Kerry" tẹ́lẹ̀.
Wikimedia Commons ní àwọn amóunmáwòrán bíbátan mọ́: Kerry Washington |