Ketu, Nigeria
Ketu jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìlú ní Ìpínlẹ̀ Èkó, Nàìjíríà . Ó wà nítòsí Mile 12. Àgbègbè náà ní èka kan ní Ile ijọsin Foursquare Gospel. Ìjọba àgbègbè Ìbílẹ̀ Idagbasoke Igbimọ Agbegbe Agboyi-Ketu (LCDA) jẹ́ ọ̀kan lára awọn ìjọba àgbègbè ìbílè metadinlogota tí ó wà ní Ìpínlẹ̀ Èkó, Nàìjíríà. Olú-ìlú rẹ̀ ni ìlú Alapere.
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkó télèrí, Asiwaju Bola Ahmed Tinubu, tí ó wà nípò láàrin May 29, ọdún 1999 sí May 29, ni ọdun 2007 ní ó dá ìjọba ìbílẹ̀ náà lè. Ó pín àgbègbè rẹ̀ pẹ̀lú Agbegbe Idagbasoke Igbimọ Agbegbe Ikosi-Isheri (LCDA), Ijọba Ibile Kosofe àti Agbegbe Idagbasoke Igbimọ Agbegbe Ikorodu West (LCDA).