Kevin McDaid
Kevin McDaid (tí a bí ní ọjọ́ keje oṣù kẹta ọdún 1984) jẹ́ akọrin ará ìlú Gẹ̀ẹ́sì. Orílè-èdè Nàìjíríà ni wọ́n bí Kevin sí tí wọ́n sì tọọ dàgbà ni ìlú England ni Newcastle upon Tyne. Wọ́n mú dáradára gégé bíi ọmọ ẹgbẹ́ ti British boy band V, èyí tí ó darapọ̀ mọ́ ní ọdún 2003 pẹ̀lú àwọn ọmọkùnrin mérin mìíràn. Ẹgbẹ́ náà ní àpẹẹrẹ àṣeyọrí mẹ́ta ní àkókò ọdún 2004 kí ó tọ́ di wípé wọ́n pínyà ní oṣù Kejì ọdún 2005,, èyí tí kò tó ọdún kan léhìn tí wọ́n gbé orin wọ́n àkọ́kọ́ jáde.
Kevin McDaid | |
---|---|
Orúkọ àbísọ | Kevin McDaid |
Ọjọ́ìbí | 7 Oṣù Kẹta 1984 Nàìjíríà |
Irú orin | Pop |
Occupation(s) | Singer, photographer |
Instruments | Vocals |
Years active | 2004–2005 |
Associated acts | V |
Ó ń ṣiṣẹ́ báyì gẹ́gẹ́ bíi olùkọ́ni ti ara rẹ̀. [1]
Ìgbésí ayé rẹ
àtúnṣeNí oṣù kejo ọdún 2005, wọ́n kéke rẹ̀ nínú ìwé ìròyìn The Sun gẹ̀gẹ̀ bíi ọ̀rẹ́kùnrin ọlọ́jọ́-pípẹ́ tii ọmọ ẹgbẹ́ Westlife, Mark Freehily.[2] Wọ́n gbé àwọn tọkọtaya náà jáde lórí abala àkọ́kọ́ ti ìwé ìròhìn Attitude[3][4] èyí tí ó jáde ní oṣù Kejìlá ọdún 2007. [5] Wọ́n ṣe àdéhùn ìgbéyàwó ní ọjọ́kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù kínní ọdún 2010. Ṣùgbọ́n ó tipẹ́ tí wọ́n ti pínyà.
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2021-04-16. Retrieved 2021-09-23.
- ↑ "Gay Belfast News Page August 2005". gaybelfast.net. 2011-07-23. Archived from the original on 2011-07-23. Retrieved 2021-09-24. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "LogoTV". Logo TV. Retrieved 2021-09-24.
- ↑ "Westlife star wants to be a father". RTE.ie. 2011-03-26. Retrieved 2021-09-24.
- ↑ "Westlife star wants to be a father". Raidió Teilifís Éireann. http://www.rte.ie/ten/2011/0326/westlife.html. Retrieved 11 May 2015.