Kiliṣi
Kílìṣi jẹ́ irúfẹ̀ ẹran ìpapánu tí ó ṣẹ̀ wá láti ẹ̀yà àwọn Haúsá. Ó jẹ́ oríṣi ẹran tí wọ́n maá n gé sí pẹlẹbẹ tí wọ́n sì tún maá n sa sóòrùn, lẹ́yìn ìgbà tí wọ́n bá ti rìí bọ omi ata tí wọ́n ti pọ̀ mọ́ àwọn èrònjà mìíràn.