Kim Jong-il
Àdàkọ:Contains Korean text Àdàkọ:Pp-semi-blp
Kim Jong-il | |
---|---|
Chosŏn'gŭl | 김정일 |
McCune–Reischauer | Kim Chŏngil |
Revised Romanization | Gim Jeong(-)il |
Kim Jong-il, abiso Yuri Irsenovich Kim (gegebi akoole Sofieti se fihan)[2][3][4][5] (ojoibi 16 February 1941 (akoole Sofieti) tabi 16 February 1942 (akoole Korea Ariwa) – 17 December 2011), ni Olori Gigajulo orile-ede Oseluarralu awon Eniyan Olominira ile Korea (Korea Ariwa). Ohun ni Alaga Ile-ise Igbimo Abo Orile-ede, Akowe Agba Egbe awon Osise ile Korea, egbe oselu to unsejoba lati 1948, ati Alase Gigajujo Akogun awon Eniyan Korea, to je akogun ekerin to tobijulo lagbaye. Ni April 2009, Korea Ariwa tun ofin igbsgbepo re se lati tokasi Jong-il bi "Olori Gigajulo".[6] Bakanna won tun unpe ni "Olori wa Owon", "Baba wa", "Ologun" ati "Generalissimo".[7]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ "N. Korean leader Kim dead: state TV". Archived from the original on 8 January 2012. http://www.google.com/hostednews/afp/article/ALeqM5ggTRbHnVT9qA8_cbG0p5dkbChBvA?docId=CNG.f422d650d5b8ced9ed3fbdc8e3558b87.e1. Retrieved 19 December 2011.
- ↑ Chung, Byoung-sun (2002-08-22), "Sergeyevna Remembers Kim Jong Il", The Chosun Ilbo, archived from the original on 2007-03-11, retrieved 2007-02-19
- ↑ Sheets, Lawrence (2004-02-12), "A Visit to Kim Jong Il's Russian Birthplace", National Public Radio, retrieved 2007-02-19
- ↑ http://transcripts.cnn.com/TRANSCRIPTS/0607/05/i_ins.01.html
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2012-01-08. Retrieved 2011-11-12.
- ↑ McGivering, Jill (29 September 2009). "N Korea constitution bolsters Kim". BBC News. http://news.bbc.co.uk/2/hi/asia-pacific/8279830.stm. Retrieved 7 May 2010.
- ↑ http://www.imdb.com/title/tt0456012/