Saphine Kirenga jẹ́ obìnrin osere ara Rùwándà. Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn òṣèré tẹlifíṣọ̀nù tí ó gbajúmọ̀ jùlọ ní orílẹ̀-èdè Rùwándà. Ó ti kópa nínu ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn fíìmù bíi The Chains of Love, Dreams, Sakabaka, Rwasibo, Seburikoko, Urugamba àti The Secret of Happiness.[1] Ó tún maá n ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bi òṣìṣẹ́ ìlera.[2]

Saphine Kirenga
Ọjọ́ìbíSaphine Kirenga
25 September
Rwanda
Orílẹ̀-èdèRwandan
Iṣẹ́Actress
Ìgbà iṣẹ́2010–present
Olólùfẹ́Sebera Eric (2015)

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "THINK ABOUT SAPHINE'S MOST IMPORTANT PLAYER TO BRING NEWS WITH BOY". celebzmagazine. Archived from the original on 3 August 2021. Retrieved 16 October 2020. 
  2. "Team Mutoni". Mutoni TV. Retrieved 16 October 2020. 

Àwọn ìtakùn Ìjásóde

àtúnṣe